ONIWASU:- PST BABALOLA.
AKORI:- LĀLA ALAGBASE TAN.
LESSON:- ONIWASU 2:18-24.
Gbogbo eda enia ninu aiye, alagbase ni a ję ninu ogba ajara Olorun.

Aiye yi je ogba ajara Olorun awa eda inu aiye je alagbase ninu ogba ajara Olorun. Alagbase ki duro pe ninu ogba ajara nitori isę alagbase ki pę titi ninu ogba ajara.

Alagbase ki mu ohun kan kuro ninu ogba ajara, bi o ba se wa sinu ogba ajara beni o se ma nkuro nitori ogba ajara kise tire.

Job 1:21 "Wipe, Nihoho ni mo ti inu iya mi jade wa, nihoho ni emi o si tun pada lo sibe: Oluwa fifunni Oluwa si gba lo, ibukun li oruko Oluwa"

Ki gbogbo eda alaye mo daju wipe, gbogbo ohun ti a ni ninu aiye yio tan lojo kan, ko si eda alaye ti yio mu nkankan kuro ninu aiye lojo ti a ba ma kuro ninu aiye.

Oniwasu 1:2-3 "Asan inu asan, oniwasu na wipe, asan inu asan; gbogbo re asan ni!
Ere kili enia je ninu gbogbo lāla re ti o se labe ōrun"

Aiye kise ibi ti a ti le ma reti isimi ti o pę titi nitori aiye gan wa fun igba die ni.

Psalm 89:47 "Ranti bi ojo mi ti kuru to; ese ti iwo ha da gbogbo enia lasan?

Gbogbo igbiyanju wa ninu aiye pelu gbogbo ohun meremere ti a kojo laiye asan ni.

Oniwasu 2:22 "Nitoripe kili enia ni ninu gbogbo lāla re ti o fi nse lāla labe ōrun?

Gbogbo eda alaye to nbe ninu aiye, a o se alabapade iku lojo kan, iku ni yio fi opin si gbogbo lāla wa ninu aiye.

Job 30:23 "Emi sa mo wipe iwo yio mun mi lo sinu iku, ati sile apejo fun gbogbo alaye"

Ni ojo ti enia ba ti min imin ikeyin ninu aiye, lojo na ni lāla alagbase re tan ninu aiye.

IBEERE MI NIYI:
1. Ni ojo wo ni lāla wa yio tan ninu aiye?
2. Kinni ohun ti a oo mu kuro ninu aiye?
3. Nibo ni a o pari irin-ajo na si?
ONIWASU:- PST BABALOLA. AKORI:- LĀLA ALAGBASE TAN. LESSON:- ONIWASU 2:18-24. Gbogbo eda enia ninu aiye, alagbase ni a ję ninu ogba ajara Olorun. Aiye yi je ogba ajara Olorun awa eda inu aiye je alagbase ninu ogba ajara Olorun. Alagbase ki duro pe ninu ogba ajara nitori isę alagbase ki pę titi ninu ogba ajara. Alagbase ki mu ohun kan kuro ninu ogba ajara, bi o ba se wa sinu ogba ajara beni o se ma nkuro nitori ogba ajara kise tire. Job 1:21 "Wipe, Nihoho ni mo ti inu iya mi jade wa, nihoho ni emi o si tun pada lo sibe: Oluwa fifunni Oluwa si gba lo, ibukun li oruko Oluwa" Ki gbogbo eda alaye mo daju wipe, gbogbo ohun ti a ni ninu aiye yio tan lojo kan, ko si eda alaye ti yio mu nkankan kuro ninu aiye lojo ti a ba ma kuro ninu aiye. Oniwasu 1:2-3 "Asan inu asan, oniwasu na wipe, asan inu asan; gbogbo re asan ni! Ere kili enia je ninu gbogbo lāla re ti o se labe ōrun" Aiye kise ibi ti a ti le ma reti isimi ti o pę titi nitori aiye gan wa fun igba die ni. Psalm 89:47 "Ranti bi ojo mi ti kuru to; ese ti iwo ha da gbogbo enia lasan? Gbogbo igbiyanju wa ninu aiye pelu gbogbo ohun meremere ti a kojo laiye asan ni. Oniwasu 2:22 "Nitoripe kili enia ni ninu gbogbo lāla re ti o fi nse lāla labe ōrun? Gbogbo eda alaye to nbe ninu aiye, a o se alabapade iku lojo kan, iku ni yio fi opin si gbogbo lāla wa ninu aiye. Job 30:23 "Emi sa mo wipe iwo yio mun mi lo sinu iku, ati sile apejo fun gbogbo alaye" Ni ojo ti enia ba ti min imin ikeyin ninu aiye, lojo na ni lāla alagbase re tan ninu aiye. IBEERE MI NIYI: 1. Ni ojo wo ni lāla wa yio tan ninu aiye? 2. Kinni ohun ti a oo mu kuro ninu aiye? 3. Nibo ni a o pari irin-ajo na si?
Positive
1
0 Comments 0 Shares 0 Reviews
Sponsored
Sponsored
Sponsored
Sponsored
Sponsored
Sponsored